èsin ati orilè-ede Naijiria
About The Episode
Eyin olugbo wa, a kuu dede asiko yi... Itan omo Naijiria la tun mu tò yin wa. Lonii, a o sòrò nipa èsin ati orilè-ede Naijiria. Gbogbo wa la mò bi òrò èsin se pataki ni orilè-ede ti a wa yi. Ki lo faa ti orilè-ede Naijiria se ri bo ti wa loni yi pèlu bi a ti n se èsin to? E o maa gbó èkunréré rè lori etoo toni. Èbun gigabyte kan (1000mb) wa fun eni to ba kókó dahun ibeere ti o wa ni isalè yi: *Ki ni èkó pataki ti a le ri kó ni etoo toni?* E fi idahun naa ransé si WhatsApp number yi: +2348133871480 --- Send in a voice message: https://anchor.fm/thenigerianstorypodcast/message

Add Comment
comments
More episodes
Loading...